Lateef Adedimeji ati Mobimpe sekojade awon ibeta ti won bi loni,e wa gbo oruko awon omo naa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Thursday, May 7, 2026

Lateef Adedimeji ati Mobimpe sekojade awon ibeta ti won bi loni,e wa gbo oruko awon omo naa

Gbogbo awon ololufe gbajumo oseretiata nni,Lateef Adedimeji ati Mobimpe ti won bi ibeta laipe yii lo pejo sile won ni Lekki ipinle Eko lati ba won sekomojade awon ibeta.
Rahman Taiwo,Raheem Kehinde ati Rokeeb Idowu loruko awon eta oko.

No comments:

Post a Comment

Pages