Ile ẹjọ sọ pe,ẹsun ti wọn fi kan Ori ade yii ko lẹsẹ nilẹ rara,koda awọn to gbe kabiesi lọ sile ẹjọ tun san ilaji miliọọnu naira gẹgẹ bii owo itanran ati biba kabiesi lorukọ jẹ.
Niṣe ni inu awọn ọmọ bibi ilu Irọ n dun yugba lasiko yii pẹlu bi Ọba wọn ti wọn fẹran daadaa ṣe jawe olubori nilẹ ẹjọ.
Toyin Agbọlade(akọroyin)
No comments:
Post a Comment