Okan pataki ni Sheik Abdulganiy Ajibade Akewusola je laarin awon Aafa ti Olorun n lo fun itusile gbogbo eda eeyan lasiko yii.
Olorun nidahun si adura gege bii oruko re je okan ninu awon Aafa to je pe Kuraani ati agbara adura nikan ni too lo lati fi be Olorun lorii isorokisoro ti eeyan n dojuko.
Aafa Ajibade tun je olufunni nitori igbagbo re ni pe Olorun maa n bukun enikeni to ba n fun omonikeji re ninu die to ni,Aafa yii tun ni oludasile Ile ise Asofam nidiroko, onisowo epo petiroolu ni pelu,o tun ni Ile ise ti won ti nta eja, ti o si je pe ko sibikibi ti e ba fe ki won ti wa ta eja ati tolotolo fun yin ti oko ti won fi nko eja kiri ko ni i de.
Boya iwo wa n dojuko oniruuru isoro bii alakala,ounje oju oorun,airi oko tabi Aya,promise and fail,aisan lago ara tete maa lo si odo Aafa Akewusola ni ilu Idiroko nipinle Ogun, lati ibikibi ti e ti n bo, e gbe okada nilu idiroko de Ile Sheik Akewusola ni Okoro Ojuroko.
Idaniloju wa pe pelu agbara adura Olorun yoo yanju isoro naa.
No comments:
Post a Comment