
Were ni asiri Oro naa tu sita l'ose to koja pe Sefiu Also eniti awon ti e mo si agbara orin Fuji gan an lo ye ki Oba Fatai Akamo iyen Olu Itori pe gege bii Olorin lojo ayeye ojo ibi ogota odun re dipo Wasiu Ayinde to pe lati wa korin lojo naa.
Gege bi a se gbo pe,Oba Akamo ti pe Sefiu lati wa se rekoodu fun ayeye ojo ibi re yii ti Sefiu si so fun Oba Fatai pe milionu meji naira ni oun yoo gba sugbon ti Oba Akamo fun un ni idaji milionu pe ki o koko lo se rekoodu naa wa.
A gbo pe Sefiu ra aso ati bata lati fi ya ise naa leyin to mu ise naa lo fun Oba Akamo ni kabiyesi wa seleri lati pe e gege bii Olorin lojo ayeye ojo ibi re.
Ohun iyalenu lo je fun Sefiu pe Wasiu Ayinde ni oba alaye yii pe,ti kabiyesi si tun ko lati San owo to je Sefiu.Ibi ayeye kan to gbajumo sorosoro to n je Kasnaty se nilu Abeokura ni Sefiu ti soro yii jade to si so pe eleda oun yoo da a fun Oba Akamo.
No comments:
Post a Comment