Inu Gbogan Mapo nilu Ibadan ko gba ero lojo satide to koja nigba ti Alaaji Oderinlo je oye Aare Alaranse Adinni fun gbogbo ipinle Oyo.Fadilat Sheik Abdulganiy Abubakry Agbotomokekere lo we lawaani oye le baba oloye tuntun Lori lojo naa.
Inu mosalasi nla to wa ninu Oja oba ni ayeye wiwe lawaani ti waye nigbati jije ati mimu waye ninu Gbogan Mapo nibi ti oba orin Saheed Osupa ti da awon eeyan laraya.
Nigbati Alaaji Oderinlo n ba wa soro lo to dupe lowo Olubadan ti Ile Ibadan oba Soliu Ajeoguguniso fun aduroti won ati oba Aileru iyen Onimushin ti Mushin ti won je oba Alade to wa nikale lojo naa .
Adura wa nileese wa ni pe oye a mori o.
No comments:
Post a Comment