Bimbo sayeye odun keji igbeyawo re, bee lo dupe lowo Olorun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, October 7, 2020

Bimbo sayeye odun keji igbeyawo re, bee lo dupe lowo Olorun

Gbajumo Osere tiata nni ti oun naa wa l'ara awon obinrin to n ta kirimu to le so eeyan dudu di funfun laarin ojo die, iyen Bimbo Ogunnowo n dupe lowo Olorun fun ti ayeye odun meji to ti segbeyawo pelu ololufe re ti oun naa je adari fiimu agbelewo iyen Ogbeni Okiki Afolayan.

Ti e o ba gbagbe pe odun meji seyin ni awon ololufe mejeeji yii segbeyawo alariwo nilu Eko, ti iya olomo kan yii si ti so pe igbese to dara ni oun gbe nipa yiyan Okiki gege bii ololufe oun, bee ni oun si dupe pe o ti pe odun meji bayii ti oun ti segbeyawo pelu re, ti oun ko si kabamo rara.

No comments:

Post a Comment

Pages