O sele! Aye oloba ni Seun Egbegbe n je l'ogba ewon kirikiri - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, October 7, 2020

O sele! Aye oloba ni Seun Egbegbe n je l'ogba ewon kirikiri

Kii se iroyin mo pe omo jayejaye nni to tun feran awon olorin Fuji iyen Seun Egbegbe wa ninu ogba ewon kirikiri sugbon to tun ti foju bale ejo lojo tuside ose yii, sugbon to je ohun iyalenu pe nise ni awo re tun n dan si i, ni eyi to tumo si pe igbadun ti ki i se kekere ni Ogbeni Seun Abdulkarim gege bi i oruko re nje l'ogba ewon.

No comments:

Post a Comment

Pages