Ope o! Neymar loun setan lati pada si Barcelona - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, November 2, 2020

Ope o! Neymar loun setan lati pada si Barcelona


Gbogbo eto lo ti pari patapata fun agbaboolu to n gba owo iwaju fun iko egbe agbaboolu Paris Saint-Germain (PSG), iyen Neymar lati pada sinu iko egbe agbaboolu Barcelona.

Odun 2021 to n bo ni Neymar yoo lo sinu egbe agbaboolu Barcelona, leyin bi osu mejidinlogun t'awon eeyan ti n f'oju sona fun un.

No comments:

Post a Comment

Pages