Wasiu Ayinde ti ni ipenija ese, opa lo fi n rin kiri bayii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, November 30, 2020

Wasiu Ayinde ti ni ipenija ese, opa lo fi n rin kiri bayii



Asiko yii kii se asiko to dara fun Olori awon onifuji rara pelu bi Mayegun Ile Yoruba iyen Alaaji Wasiu Ayinde se ti ni ipenija ese to si je pe opa lo fi n rin kiri bayii.

Ose to koja ni gbajumo sorosoro ori redio nni to tun fi ilu Ibadan sebugbe iyen oloye Kola Olotu sabewo si Ile Wasiu to wa ni ijebu ode,nibe ni asiri ti tu pe opa ni Oluaye fi n rin bayii.

Ti e o ba gbagbe pe ode ariya ti Wasiu yoo lo leyin koro lo je pe ori ijoko ni Oluaye ti korin lati ibere de opin.

No comments:

Post a Comment

Pages