Irole ojo sannde ose yii gan an ni iroyin naa be sita pe ajo to n ri si Oro isowo ilu mokumoku iyen ajo Efcc ti gbe Alaaji Musiliu Akinsanya to je Olori ati oga fun awon onimoto nipinle Eko lati fi Oro wa a lenu wo ni ofiisi won to wa ni ilu Eko.
A gbo pe ajo Efcc fe bere ibi ti Oluomo gege bi oruko imagine re ti n ri owo to n na kiri ati pe won fe mo bi owo se n wole fun un.
A gbo pe ose die ni amugbalegbe Oluomo iyen Koko Zaria si Ile itura kan silu Eko ti M.C Oluomo si n na owo beeli beeli fun Oganla Fuji iyen Wasiu Alabi Pasuma ti won pe gege bi olorin lojo naa.
No comments:
Post a Comment