Oni yii gan an ni ojo ibi Ogbeni Taofik Afolabi oga agba ileese Ojutole blog - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, December 11, 2020

Oni yii gan an ni ojo ibi Ogbeni Taofik Afolabi oga agba ileese Ojutole blog


Gbogbo ojo kejila ninu osu kejila ni ayajo ojo ibi oga agba ni ileese Ojutole iyen Ogbeni Taofik Afolabi.

Eeyan wa daadaa ni Ogbeni Ojutole ti o si feran ilosiwaju awon eeyan to wa layika re,kii se ahun beeni kii se onilara ,inu re maa n dun si igbega ati ilosiwaju awon to wa layika re.

A wa n fi asiko yii ki eeyan wa daadaa fun ti ayeye ojo ibi re to waye loni ti a si gbadura pe emi yin yoo se opo odun laye,oga wa owon, eeyan iyi. 

No comments:

Post a Comment

Pages