Awuyewuye ti n lo nigboro tipe pe aarin Olori ebi Arabambi iyen Wasiu Ayinde to tun je Mayegun Ile Yoruba ati Alaaja Asabi Baritide ko gun rege nitori Oro kan ti Wasiu so nigba kan pe oun gan an ni oludasile orin Fuji, ti eyi si mu Barimade soro buruku si Wasiu nigba naa.
Sugbon ti a gbo lose to koja pe nibi ode ariya kan nilu Ilorin nibiti Oluaye ti je olorin nibi ayeye naa ti Barimade wa nibe la gbo pe awon olorin mejeeji yii ti pari ija gbigbona aarin won naa.
Inu ayo ati idunnu ni opo olorin Fuji wa bayii pelu bi ife ti se pada saarin awon olorin mejeeji yii.A tun gbo pe Wasiu ati Alaaji Kollington Ayinla to pari ija aarin won pelu.
No comments:
Post a Comment