Agbegbe Council ni Ikotun nipinle Eko ni Ayeye naa yoo ti waye leyin irun jimo lojo naa.Alaaja Barimade so fun akoroyin Tojubole pe owuro ojo naa ni oun atawon igbimo ayeye yoo sabewo si Ile awon omo alailobi lati fi ebun onje ,aso ati owo ta awon omo yii lore.Leyin eyi ni waasi yoo bere nibi ti Sheik Salaudeen Almubarak yoo ti soro lori 'Ififunni lasiko Ramadan,kini ere to wa nibe fun olufunni ati eniti a fi fun.Awon alejo Pataki ni yoo wa nikale lojo naa bii baba Adinni Naijiria atawon eeyan jankanjankan miiran lawujo.


No comments:
Post a Comment