Oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS ki Ọọniriṣa ku oriire ọjọ ibi aadọta ọdun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, October 23, 2024

Oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS ki Ọọniriṣa ku oriire ọjọ ibi aadọta ọdun


Toyin Agbọlade
Ogunjọ oṣu yii ni oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkantan ninu tita ilẹ kaakiri orilẹ ede yii,Aarẹ Adetọla Emmanuelking ṣabẹwo saafin Ọọniriṣa ọba Ẹnitan Ogunwusi.
Aarẹ Emmanuelking so iwulo gbigbe asa ati ise laruge ti eyi si ti je ki idagbasoke ba ile Oodua lapapo.
'Idagbasoke  ni i se pelu ipile ninu iran yoruba ati asa ni orile ede yii lapapo ti o si je ohun imuyangan fun wa ti a si gbodo ri i pe ,awon iran to n bo naa mo nipa asa'eyi lawon ohun ti oludasile ileese naa so laafin Ọọnirisa.
Aare Emmanuelking tun wa gbadun fun Ooni lojo naa pe,ki igba re tubo tu iran yoruba lara,ki Olodumare fun un ni ogbon,imo ati oye pelu alaafia ati emi gigun.
O tun wa so pe,ileese Adrons n je ki ife ati irepo wa laarin awon oba alade ,o de tun mo riri won lawujo ti ileese naa ko tun fi oro itesiwaju iran yoruba sere rara.
Ooni naa wa dupe lowo Aare Emmanuelking atawon oga ileese naa bii,Arabinrin Adenike Ajobo ti oba alade naa si gbadura fun ileese naa ati orile ede yii.
Boya iwo fe mo si i nipa ileese Adrons tabi o fe ba won dowo po,tete kan si ofiisi won to ba wa nitosi odo e,ADRONS araba ni laarin awọn to n ta ilẹ.

No comments:

Post a Comment

Pages